Barry Jhay Lyrics
Embrace the power of words and music with the heartfelt lyrics of Barry Jhay‘s Eleduwa.
Barry Jhay – Eleduwa Lyrics
Intro
Ojo buruku lonisotun’un
Baba sho’n gbo oun aiye’n so
Eledua.. eyin ni akoko ninu gbogbo nkan
Keto da aye ati orun
And that na why me I put you first in everything I do
O’ma ma se olorun mi
Opo opo ooo
Chorus
Ibi tan ni ki gbegbe magbe, lofi shey apartey
Ibi tan ni ki tete màté lò ló shey vacey
Nigba tan tu wa’n soro, woni mio mo ju’olorun lo
Baba sho’ngbo oun aiye so
Ayun lo, ayun bo lowo yun enu
Iko o’ni ko bàlà mi lè se
Ni ola olorun
La tio ni lo, ki onaa mi kola peregede
La to ni lo, magbe ori ile yii seun rere
Verse
Eyin to laye!
E gbo oun mi se ase IFA
Abiyamo aiye!!
E duro timi ki’n mase jabo oo
Ikoko lafi de’e
Lodo IFA ooo
Karaye mafowo bo agogo mi lenu ee
Ti’n ba lu se ni koma dun’n
Chorus
Ibi tan ni ki gbegbe magbe, lofi shey apartey
Ibi tan ni ki tete màté lò ló shey vacey
Nigba tan tu wa’n soro, woni mio mo ju’olorun lo
Baba sho’ngbo oun aiye so
Ayun lo, ayun bo lowo yun enu
Iko o’ni ko bàlà mi lè sé, ni ola olorun
La tio ni lo, ki onaa mi kola peregede
La to ni lo, magbe ori ile yii seun rere
Outro
La tio ni lo, ki onaa mi kola peregede
La to ni lo, magbe ori ile yii seun rere
Want to keep up with the latest songs? Check out more song lyrics here and follow us on X and Facebook